← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú I. Joh 4:18

Ìgboyà
Ọ̀sẹ̀ kan
Kọ́ ohun tí Bíbélì sọ nípa ìgboyà. Ètò kíkà “Ìgboyà” rán àwọn onígbàgbọ́ létí ẹni tí wọ́n jẹ́ nínú Kristi àti nínú ìjọba Ọlọ́run. Nígbà tí a bá jẹ́ ti Ọlọrun, a ní òmìnira láti súnmọ́-On tààrà. Kà lẹ́ẹ̀kansi - tàbí bóyá fún ìgbà àkọ́kọ́ - àwọn ìdánilójú pé ipò rẹ nínú ìdílé Ọlọrun wà síbẹ̀.