1
Joh 9:4
Bibeli Mimọ
Emi kò le ṣe alaiṣe iṣẹ ẹniti o rán mi, nigbati iṣe ọsan: oru mbọ̀ wá nigbati ẹnikan kì o le ṣe iṣẹ.
Bandingkan
Telusuri Joh 9:4
2
Joh 9:5
Niwọn igba ti mo wà li aiye, emi ni imọlẹ aiye.
Telusuri Joh 9:5
3
Joh 9:2-3
Awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si bi i lẽre, wipe. Olukọni, tani dẹṣẹ, ọkunrin yi tabi awọn obi rẹ̀, ti a fi bi i li afọju? Jesu dahùn pe, Kì iṣe nitoriti ọkunrin yi dẹṣẹ, tabi awọn obi rẹ̀: ṣugbọn ki a le fi iṣẹ Ọlọrun hàn lara rẹ̀.
Telusuri Joh 9:2-3
4
Joh 9:39
Jesu si wipe, Nitori idajọ ni mo ṣe wá si aiye yi, ki awọn ti kò riran, le riran; ati ki awọn ti o riran le di afọju.
Telusuri Joh 9:39
Beranda
Alkitab
Rencana
Video