1
Joh 8:12
Bibeli Mimọ
Jesu si tun sọ fun wọn pe, Emi ni imọlẹ aiye; ẹniti o ba tọ̀ mi lẹhin kì yio rìn ninu òkunkun, ṣugbọn yio ni imọlẹ ìye.
Bandingkan
Telusuri Joh 8:12
2
Joh 8:32
Ẹ ó si mọ̀ otitọ, otitọ yio si sọ nyin di omnira.
Telusuri Joh 8:32
3
Joh 8:31
Nitorina Jesu wi fun awọn Ju ti o gbà a gbọ́ pe, Bi ẹnyin ba duro ninu ọ̀rọ mi, nigbana li ẹnyin jẹ ọmọ-ẹhin mi nitõtọ.
Telusuri Joh 8:31
4
Joh 8:36
Nitorina bi Ọmọ ba sọ nyin di omnira, ẹ ó di omnira nitõtọ.
Telusuri Joh 8:36
5
Joh 8:7
Ṣugbọn nigbati nwọn mbi i lẽre sibẹsibẹ, o gbé ara rẹ̀ soke, o si wi fun wọn pe, Ẹniti o ba ṣe ailẹṣẹ ninu nyin, jẹ ki o kọ́ sọ okuta lù u.
Telusuri Joh 8:7
6
Joh 8:34
Jesu da wọn lohun pe, Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun nyin, Ẹnikẹni ti o ba ndẹṣẹ, on li ẹrú ẹ̀ṣẹ.
Telusuri Joh 8:34
7
Joh 8:10-11
Jesu si gbé ara rẹ̀ soke, o si wi fun u pe, Obinrin yi, awọn dà? Kò si ẹnikan ti o da ọ lẹbi? O wipe, Kò si ẹnikan, Oluwa. Jesu si wi fun u pe, Bẹ̃li emi na kò da ọ lẹbi: mã lọ, lati igbayi lọ má dẹṣẹ̀ mọ́.
Telusuri Joh 8:10-11
Beranda
Alkitab
Rencana
Video