I. Kro 8
8
Àwọn Ìran Bẹnjamini
1BENJAMINI si bi Bela, akọbi rẹ̀, Aṣbeli ekeji, ati Ahara ẹkẹta,
2Noha ẹkẹrin, ati Rafa ẹkarun.
3Awọn ọmọ Bela ni Addari, ati Gera, ati Abihudi,
4Ati Abiṣua, ati Naamani, ati Ahoa,
5Ati Gera, ati Ṣefufani, ati Huramu,
6Wọnyi si li awọn ọmọ Ehudi: wọnyi li awọn olori baba wọn, ti nwọn ngbe Geba, nwọn si ko wọn lọ si Mahanati ni igbekun.
7Ati Naamani, ati Ahiah, ati Gera, o si ko wọn kuro, o si bi Ussa ati Ahihudi.
8Ṣaharaimu si bi ọmọ ni ilẹ Moabu; lẹhin igbati o ti ran wọn lọ tan; Huṣimu ati Baera si li awọn aya rẹ̀.
9Hodeṣi, aya rẹ̀ si bi, Jobabu, ati Sibia, ati Meṣa, ati Malkama fun u,
10Ati Jeusi, ati Ṣokia, ati Mirma. Wọnyi li awọn ọmọ rẹ̀, olori awọn baba.
11Huṣimu si bi Ahitubu ati Elpaali fun u.
12Awọn ọmọ Elpaali, Eberi, ati Miṣamu ati Ṣameri, ẹniti o kọ́ Ono ati Lodi pẹlu ilu wọn:
Àwọn Ará Bẹnjamini tí wọ́n wà ní Gati ati Aijalonii
13Beria pẹlu, ati Ṣema, ti nwọn iṣe olori awọn baba awọn ara Ajaloni, awọn ti o le awọn ara Gati kuro.
14Ati Ahio, Ṣaṣaki, Jerimotu,
15Ati Sebadiah, ati Aradi, ati Aderi,
16Ati Mikaeli, ati Ispa, ati Joha, ni awọn ọmọ Beria;
Àwọn Ará Bẹnjamini ní Jerusalẹmu
17Ati Sobadiah, ati Meṣullamu, ati Heseki, ati Heberi.
18Iṣmeri pẹlu, ati Jeslia, ati Jobabu, ni awọn ọmọ Elpaali.
19Ati Jakimu, ati Sikri, ati Sabdi,
20Ati Elienai, ati Siltai, ati Elieli,
21Ati Adaiah, ati Beraiah, ati Ṣimrati ni awọn ọmọ Ṣimhi;
22Ati Iṣpani, ati Eberi, ati Elieli,
23Ati Abdoni, ati Sikri, ati Hanani,
24Ati Hananiah, ati Elamu, ati Antotiah,
25Ati Ifediah, ati Penueli, ni awọn ọmọ Ṣaṣaki;
26Ati Samṣerai, ati Sehariah, ati Ataliah,
27Ati Jaresiah, ati Eliah, ati Sikri, ni awọn ọmọ Jerohamu.
28Wọnyi li olori awọn baba, nipa iran wọn, awọn olori. Awọn wọnyi ni ngbe Jerusalemu.
Àwọn Ará Bẹnjamini tí Wọ́n Wà ní Gibeoni ati Jerusalẹmu
29Ni Gibeoni ni baba Gibeoni si ngbe; orukọ aya ẹniti ijẹ Maaka:
30Ọmọ rẹ̀ akọbi si ni Abdoni, ati Suri, ati Kiṣi, ati Baali, ati Nadabu,
31Ati Gedori, ati Ahio, ati Sakeri,
32Mikloti si bi Ṣimea. Awọn wọnyi pẹlu si mba awọn arakunrin wọn gbe Jerusalemu, nwọn kọju si ara wọn.
Ìdílé Saulu Ọba
33Neri si bi Kiṣi, ati Kiṣi si bi Saulu, ati Saulu si bi Jonatani, ati Milkiṣua, ati Abinadabu, ati Esbaali.
34Ọmọ Jonatani si ni Meribaali; Meribaali si bi Mika.
35Awọn ọmọ Mika ni Pitoni ati Meleki, ati Tarea, ati Ahasi.
36Ahasi si bi Jehoadda; ati Jehoadda si bi Alemeti, ati Asmafeti, ati Simri: Simri si bi Mosa;
37Mosa si bi Binea, Rafa ọmọ rẹ̀, Eleasari ọmọ rẹ̀, Aseli ọmọ rẹ̀:
38Aseli si ni ọmọkunrin mẹfa, orukọ wọn ni wọnyi, Asrikamu, Bokeru, ati Iṣmaeli, ati Seraiah, ati Obadiah, ati Hanani. Gbogbo awọn wọnyi li ọmọ Aseli.
39Awọn ọmọ Eṣeki arakunrin rẹ̀ si ni Ulamu akọbi rẹ̀, Jehuṣi ekeji, ati Elifeleti ẹkẹta.
40Awọn ọmọ Ulamu si jẹ alagbara akọni ọkunrin, tafatafa, nwọn si li ọmọ pupọ ati ọmọ ọmọ adọjọ. Gbogbo wọnyi li awọn ọmọ Benjamini.
Currently Selected:
I. Kro 8: YBCV
Highlight
Share
Copy
Want to have your highlights saved across all your devices? Sign up or sign in
Yoruba Bible Crowther Version © The Bible Society of Nigeria, 2012.