Njẹ mo wi fun ọ, A dari ẹ̀ṣẹ rẹ̀ ti o pọ̀ jì i; nitoriti o ni ifẹ pipọ: ẹniti a si dari diẹ jì, on na li o ni ifẹ diẹ. O si wi fun u pe, A dari ẹ̀ṣẹ rẹ jì ọ.
Luk 7:47-48
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò