I. Kor 10:12-14
![I. Kor 10:12-14 - Nitorina ẹniti o ba rò pe on duro, ki o kiyesara, ki o má ba ṣubu.
Kò si idanwò kan ti o ti ibá nyin, bikoṣe irú eyiti o mọ niwọn fun enia: ṣugbọn olododo li Ọlọrun, ẹniti kì yio jẹ ki a dan nyin wò jù bi ẹnyin ti le gbà; ṣugbọn ti yio si ṣe ọna atiyọ pẹlu ninu idanwò na, ki ẹnyin ki o ba le gbà a.
Nitorina, ẹnyin olufẹ mi, ẹ sá fun ibọriṣa.](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2F320x320%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fstatic-youversionapi-com%2Fimages%2Fbase%2F55381%2F1280x1280.jpg&w=640&q=75)
Nitorina ẹniti o ba rò pe on duro, ki o kiyesara, ki o má ba ṣubu. Kò si idanwò kan ti o ti ibá nyin, bikoṣe irú eyiti o mọ niwọn fun enia: ṣugbọn olododo li Ọlọrun, ẹniti kì yio jẹ ki a dan nyin wò jù bi ẹnyin ti le gbà; ṣugbọn ti yio si ṣe ọna atiyọ pẹlu ninu idanwò na, ki ẹnyin ki o ba le gbà a. Nitorina, ẹnyin olufẹ mi, ẹ sá fun ibọriṣa.
I. Kor 10:12-14