Ayé àti Ìwòsàn nínú Psálmù
Ọjọ́ 181
"Orin kan lójúmọ́ a máa mú ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn jìnà. Kọ́ orí kan lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan láti inú Orin Dáfídì àti Ìwé Òwe. Ìwọ yóò ka orí mẹ́fà láti inú Orin Dáfídì l'ọ́sẹ̀ kọ̀ọ̀kan fún osù mẹ́fà àti orí kan nínú Ìwé Òwe ní ọjọọjọ́ méje. Nígbànáà ni ìwọ yíò ti paríi ìwé méjèèjì ní oṣù mẹ́fà".
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ilé-isẹ́ Ìránṣẹ́ McQueen Universal Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.mcqueenum.org
Nípa Akéde