Májẹ̀mú Àtijọ́ - Àwọn Wòólì Kékeré

Ọjọ́ 25
Ètò tó rọrùn yí yíò mú o kà nípa àwọn wòólì kékeré inú májẹ̀mú àtijọ́. Pẹ̀lú kíka Orí ìwé díẹ̀ lójoojúmọ́, ètò yí yíò dára púpọ̀ fún kíkà olúkúlùkù tàbí ẹgbẹ́.
A pèsè ètò yí nípaṣẹ̀ YouVersion. Fún àlàyé díẹ̀ si, jọ̀wọ́ lọ sí: www.youversion.com
Nípa Akéde