Sek 14:9
Sek 14:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oluwa yio si jọba lori gbogbo aiye: li ọjọ na ni Oluwa kan yio wà, orukọ rẹ̀ yio si jẹ ọkan.
Pín
Kà Sek 14Sek 14:9 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA yóo wá jọba ní gbogbo ayé; Ọlọrun nìkan ni gbogbo aráyé yóo máa sìn nígbà náà, orúkọ kanṣoṣo ni wọn yóo sì mọ̀ ọ́n.
Pín
Kà Sek 14