Rom 8:37
Rom 8:37 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn ninu gbogbo nkan wọnyi awa jù ẹniti o ṣẹgun lọ nipa ẹniti o fẹ wa.
Pín
Kà Rom 8Rom 8:37 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn ninu gbogbo ìrírí wọnyi, a ti borí gbogbo ìṣòro nípa agbára ẹni tí ó fẹ́ràn wa.
Pín
Kà Rom 8