Rom 8:18
Rom 8:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori mo ṣíro rẹ̀ pe, ìya igba isisiyi kò yẹ lati fi ṣe akawe ogo ti a o fihàn ninu wa.
Pín
Kà Rom 8Rom 8:18 Yoruba Bible (YCE)
Mo wòye pé a kò lè fi ìyà ayé yìí wé ọlá tí Ọlọrun yóo dá wa ní ayé tí ń bọ̀ wá.
Pín
Kà Rom 8