Rom 5:3
Rom 5:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Kì si iṣe bẹ̃ nikan, ṣugbọn awa si nṣogo ninu wahalà pẹlu: bi a ti mọ̀ pe wahalà nṣiṣẹ sũru
Pín
Kà Rom 5Rom 5:3 Yoruba Bible (YCE)
Èyí nìkan kọ́. A tún ń fi àwọn ìṣòro wa ṣe ọlá, nítorí a mọ̀ pé àyọrísí ìṣòro ni ìfaradà
Pín
Kà Rom 5