Rom 4:20-22
Rom 4:20-22 Bibeli Mimọ (YBCV)
Kò fi aigbagbọ ṣiyemeji ileri Ọlọrun; ṣugbọn o le ni igbagbọ́, o nfi ogo fun Ọlọrun; Nigbati o sa ti mọ̀ dajudaju pe, ohun ti on ba ti leri, o si le ṣe e. Nitorina li a si ṣe kà a si ododo fun u.
Pín
Kà Rom 4