Rom 12:12
Rom 12:12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ mã yọ̀ ni ireti; ẹ mã mu sũru ninu ipọnju; ẹ mã duro gangan ninu adura
Pín
Kà Rom 12Rom 12:12 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ máa yọ̀ nítorí ìrètí tí ẹ ní. Ẹ máa fara da ìṣòro, kí ẹ sì tẹra mọ́ adura.
Pín
Kà Rom 12