Rom 11:35-36
Rom 11:35-36 Bibeli Mimọ (YBCV)
Tabi tali o kọ́ fifun u, ti a o si san a pada fun u? Nitori lati ọdọ rẹ̀, ati nipa rẹ̀, ati fun u li ohun gbogbo: ẹniti ogo wà fun lailai. Amin.
Pín
Kà Rom 11Tabi tali o kọ́ fifun u, ti a o si san a pada fun u? Nitori lati ọdọ rẹ̀, ati nipa rẹ̀, ati fun u li ohun gbogbo: ẹniti ogo wà fun lailai. Amin.