Rom 10:10
Rom 10:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ọkàn li a fi igbagbọ́ si ododo; ẹnu li a si fi ijẹwọ si igbala.
Pín
Kà Rom 10Rom 10:10 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí pẹlu ọkàn ni a fi ń gbàgbọ́ láti rí ìdáláre gbà. Ṣugbọn ẹnu ni a fi ń jẹ́wọ́ láti rí ìgbàlà.
Pín
Kà Rom 10