O. Daf 96:2-3
O. Daf 96:2-3 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ kọ orin sí OLUWA, ẹ yin orúkọ rẹ̀; ẹ sọ nípa ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́. Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè; ẹ sọ̀rọ̀ iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan.
Pín
Kà O. Daf 96O. Daf 96:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ kọrin si Oluwa, fi ibukún fun orukọ rẹ̀; ẹ ma fi igbala rẹ̀ hàn lati ọjọ de ọjọ. Sọ̀rọ ogo rẹ̀ lãrin awọn keferi, ati iṣẹ iyanu rẹ̀ lãrin gbogbo enia.
Pín
Kà O. Daf 96