O. Daf 88:8-9
O. Daf 88:8-9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Iwọ ti mu awọn ojulumọ mi jina si mi; iwọ si sọ mi di irira si wọn; a se mi mọ́, emi kò le jade. Oju mi nkãnu nitori ipọnju: Oluwa, emi ti npè ọ lojojumọ, emi si ti nawọ mi si ọ.
Pín
Kà O. Daf 88