Ààbò mi ń bẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run, ẹni tí ń ṣe ìgbàlà òtítọ́ ní àyà.
Abo mi mbẹ lọdọ Ọlọrun ti o nṣe igbala olotitọ li aiya.
Ọlọrun ni aláàbò mi, òun níí gba àwọn ọlọ́kàn mímọ́ là.
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò