O. Daf 55:16-17
O. Daf 55:16-17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi o ṣe ti emi ni, emi o kepè Ọlọrun; Oluwa yio si gbà mi. Li alẹ, li owurọ, ati li ọsan, li emi o ma gbadura, ti emi o si ma kigbe kikan: on o si gbohùn mi.
Pín
Kà O. Daf 55Bi o ṣe ti emi ni, emi o kepè Ọlọrun; Oluwa yio si gbà mi. Li alẹ, li owurọ, ati li ọsan, li emi o ma gbadura, ti emi o si ma kigbe kikan: on o si gbohùn mi.