Nitori Ọlọrun yi Ọlọrun wa ni lai ati lailai: on ni yio ma ṣe amọna wa titi ikú.
pe: “Ọlọrun yìí ni Ọlọrun wa, lae ati laelae. Òun ni yóo máa ṣe amọ̀nà wa títí lae.”
Nítorí Ọlọ́run yìí Ọlọ́run wà ní títí ayé, Òun ni yóò ṣe amọ̀nà wa títí dè òpin ayé.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò