Ṣãnu fun mi, Oluwa, nitori ti emi wà ninu iṣẹ́: oju mi fi ibinujẹ run, ọkàn mi ati inu mi.
Ṣàánú mi, OLUWA, nítorí pé mo wà ninu ìṣòro. Ìbànújẹ́ sọ ojú mi di bàìbàì; àárẹ̀ sì mú ọkàn ati ara mi.
Ṣàánú fún mi, ìwọ OLúWA, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú; ojú mi fi ìbìnújẹ́ sùn, ọkàn àti ara mi pẹ̀lú.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò