O. Daf 22:31
O. Daf 22:31 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nwọn o wá, nwọn o si ma sọ̀rọ ododo rẹ̀ fun awọn enia kan ti a o bí, pe, on li o ṣe eyi.
Pín
Kà O. Daf 22O. Daf 22:31 Yoruba Bible (YCE)
Wọn óo máa kéde ìgbàlà rẹ̀ fún àwọn ọmọ tí a kò tíì bí, pé, “OLUWA ló ṣe é.”
Pín
Kà O. Daf 22