Nitorina li emi ṣe fi iyìn fun ọ, Oluwa, li awujọ awọn orilẹ-ède, emi o si ma kọrin iyìn si orukọ rẹ.
Nítorí náà ni èmi ó ṣe máa yìn ọ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, OLUWA, èmi ó sì máa kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ.
Títí láéláé, èmi yóò máa yìn ọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ìwọ OLúWA; Èmi yóò sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò