Nitori ti emi mọ̀ pe Oluwa tobi, ati pe Oluwa jù gbogbo oriṣa lọ.
Èmi mọ̀ pé OLUWA tóbi, ati pé ó ju gbogbo oriṣa lọ.
Nítorí tí èmi mọ̀ pé OLúWA tóbi, àti pé Olúwa jù gbogbo òrìṣà lọ.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò