Oluwa, orukọ rẹ duro lailai; iranti rẹ Oluwa, lati iran-diran.
OLUWA, orúkọ rẹ yóo wà títí lae, òkìkí rẹ óo sì máa kàn títí ayé.
OLúWA orúkọ rẹ dúró láéláé; ìrántí rẹ OLúWA, láti ìrandíran.
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò