O. Daf 130:7-8
O. Daf 130:7-8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Israeli iwọ ni ireti niti Oluwa: nitori pe lọdọ Oluwa li ãnu wà, ati lọdọ rẹ̀ li ọ̀pọlọpọ idande wà. On o si da Israeli nidè kuro ninu ẹ̀ṣẹ rẹ̀ gbogbo