Oluwa, kọ́ mi li ọ̀na rẹ; emi o si ma pa a mọ́ de opin.
OLUWA, kọ́ mi ní ìlànà rẹ, n óo sì pa wọ́n mọ́ dé òpin.
Kọ́ mi, OLúWA, láti tẹ̀lé àṣẹ rẹ; nígbà náà ni èmi yóò pa wọ́n mọ́ dé òpin.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò