O. Daf 111:1-3
O. Daf 111:1-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ ma yìn Oluwa. Emi o ma yìn Oluwa tinutinu mi, ninu ijọ awọn ẹni diduro-ṣinṣin, ati ni ijọ enia. Iṣẹ Oluwa tobi, iwa-kiri ni fun gbogbo awọn ti o ni ifẹ rẹ̀ ninu. Iṣe rẹ̀ li ọlá on ogo, ododo rẹ̀ si duro lailai.