O. Daf 108:4-5
O. Daf 108:4-5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ti ãnu rẹ tobi jù ọrun lọ: ati otitọ rẹ titi de awọsanma. Gbé ara rẹ ga, Ọlọrun, lori awọn ọrun: ati ogo rẹ lori gbogbo aiye.