Jẹ ki awọn ẹni-irapada Oluwa ki o wi bẹ̃, ẹniti o rà pada kuro ni ọwọ ọta nì.
Kí àwọn tí OLUWA ti rà pada kí ó wí bẹ́ẹ̀, àní, àwọn tí ó yọ kúrò ninu ìpọ́njú
Jẹ́ kí àwọn ẹni ìràpadà OLúWA kí ó wí báyìí, àwọn ẹni tí ó rà padà kúrò lọ́wọ́ ọ̀tá
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò