Owe 30:29-31
Owe 30:29-31 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ohun mẹta ni mbẹ ti nrìn rere, nitõtọ, mẹrin li o dára pupọ ni ìrin rirìn: Kiniun ti o lagbara julọ ninu ẹranko, ti kò si pẹhinda fun ẹnikan; Ẹṣin ti a dì lẹgbẹ; ati obukọ; ati ọba larin awọn enia rẹ̀.
Pín
Kà Owe 30