Ẹniti o ba ro ilẹ rẹ̀ yio li ọ̀pọ onjẹ: ṣugbọn ẹniti o ba ntọ̀ enia asan lẹhin yio ni òṣi to.
Ẹni tí ń ṣiṣẹ́ oko dáradára, yóo ní oúnjẹ pupọ, ṣugbọn ẹni tí ń fi àkókò rẹ̀ ṣòfò yóo di talaka.
Ẹni tí ó bá ro ilẹ̀ rẹ̀ yóò ní oúnjẹ lọ́pọ̀lọpọ̀ ṣùgbọ́n ẹni tí ń lé ohun asán yóò kún fún òsì.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò