Owe 22:22-23
Owe 22:22-23 Yoruba Bible (YCE)
Má ja talaka lólè, nítorí pé ó jẹ́ talaka, má sì dájọ́ èké fún ẹni tí ara ń ni. Nítorí OLUWA yóo gbèjà wọn, yóo fìyà jẹ àwọn tí wọn ń jẹ wọ́n níyà.
Pín
Kà Owe 22Má ja talaka lólè, nítorí pé ó jẹ́ talaka, má sì dájọ́ èké fún ẹni tí ara ń ni. Nítorí OLUWA yóo gbèjà wọn, yóo fìyà jẹ àwọn tí wọn ń jẹ wọ́n níyà.