Owe 20:24-25
Owe 20:24-25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Irin ti enia nrìn, lati ọdọ Oluwa ni; tani ninu awọn enia ti o le mọ̀ ọ̀na rẹ̀? Idẹkùn ni fun enia lati yara ṣe ileri mimọ́, ati lẹhin ẹjẹ́, ki o ma ronu.
Pín
Kà Owe 20Owe 20:24-25 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Owe 20