Owe 20:22-23
Owe 20:22-23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Iwọ máṣe wipe, Emi o gbẹsan ibi; ṣugbọn duro de Oluwa, on o si gbà ọ. Ìwọn miran, ati òṣuwọn miran, irira ni loju Oluwa; ìwọn irẹjẹ kò si dara.
Pín
Kà Owe 20Owe 20:22-23 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Owe 20