Owe 19:27-29
Owe 19:27-29 Yoruba Bible (YCE)
Ọmọ mi, bí o bá kọ etí dídi sí ẹ̀kọ́, o óo ṣìnà kúrò ninu ìmọ̀. Ẹlẹ́rìí èké a máa kẹ́gàn ìdájọ́ òtítọ́, eniyan burúkú a máa jẹ ẹ̀ṣẹ̀ bí ẹni jẹun. Ìjìyà ti wà nílẹ̀ fún ẹlẹ́yà, a sì ti tọ́jú pàṣán sílẹ̀ fún ẹ̀yìn òmùgọ̀.
Pín
Kà Owe 19Owe 19:27-29 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọmọ mi, dẹkun ati fetisi ẹkọ́ ti imu ni ṣìna kuro ninu ọ̀rọ ìmọ. Ẹlẹri buburu fi idajọ ṣẹsin: ẹnu enia buburu si gbe aiṣedẽde mì. A pèse ọ̀rọ-idajọ fun awọn ẹlẹgàn, ati paṣan fun ẹ̀hin awọn aṣiwère.
Pín
Kà Owe 19