Owe 19:21
Owe 19:21 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ete pupọ li o wà li aiya enia; ṣugbọn ìgbimọ Oluwa, eyini ni yio duro.
Pín
Kà Owe 19Owe 19:21 Yoruba Bible (YCE)
Ọpọlọpọ ni èrò tí ó wà lọ́kàn ọmọ eniyan, ṣugbọn ìfẹ́ OLUWA ni àṣẹ.
Pín
Kà Owe 19Ete pupọ li o wà li aiya enia; ṣugbọn ìgbimọ Oluwa, eyini ni yio duro.
Ọpọlọpọ ni èrò tí ó wà lọ́kàn ọmọ eniyan, ṣugbọn ìfẹ́ OLUWA ni àṣẹ.