Owe 19:20-21
Owe 19:20-21 Bibeli Mimọ (YBCV)
Fetisi ìmọ ki o si gbà ẹkọ́, ki iwọ ki o le gbọ́n ni igbẹhin rẹ. Ete pupọ li o wà li aiya enia; ṣugbọn ìgbimọ Oluwa, eyini ni yio duro.
Pín
Kà Owe 19Owe 19:20-21 Yoruba Bible (YCE)
Gbọ́ ìmọ̀ràn kí o sì gba ẹ̀kọ́, kí o lè rí ọgbọ́n lò lẹ́yìn ọ̀la. Ọpọlọpọ ni èrò tí ó wà lọ́kàn ọmọ eniyan, ṣugbọn ìfẹ́ OLUWA ni àṣẹ.
Pín
Kà Owe 19