Aṣiwère ọmọ ni ibanujẹ baba rẹ̀: ìja aya dabi ọ̀ṣọrọ òjo.
Òmùgọ̀ ọmọ lè kó ìparun bá baba rẹ̀, iyawo oníjà dàbí omi òjò tí ń kán tó, tó, tó, láì dáwọ́ dúró.
Aṣiwèrè ọmọ jẹ́ ìparun baba rẹ̀, Aya tí ó máa ń jà sì dàbí ọ̀ṣọ̀ọ̀rọ̀ òjò.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò