Owe 18:9-10
Owe 18:9-10 Yoruba Bible (YCE)
Ẹni tí ń ṣe ìmẹ́lẹ́ lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀, ẹgbẹ́ ni òun ati ẹni tí ń ba nǹkan jẹ́. Orúkọ OLUWA jẹ́ ilé-ìṣọ́ tí ó lágbára, olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì yè.
Pín
Kà Owe 18Owe 18:9-10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹniti o lọra pẹlu ni iṣẹ rẹ̀, arakunrin jẹguduragudu enia ni. Orukọ Oluwa, ile-iṣọ agbara ni: Olododo sá wọ inu rẹ̀, o si là.
Pín
Kà Owe 18Owe 18:9-10 Yoruba Bible (YCE)
Ẹni tí ń ṣe ìmẹ́lẹ́ lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀, ẹgbẹ́ ni òun ati ẹni tí ń ba nǹkan jẹ́. Orúkọ OLUWA jẹ́ ilé-ìṣọ́ tí ó lágbára, olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì yè.
Pín
Kà Owe 18