Owe 18:2-3
Owe 18:2-3 Yoruba Bible (YCE)
Òmùgọ̀ kò ní inú dídùn sí ìmọ̀, àfi kí ó ṣá máa sọ èrò ọkàn rẹ̀. Nígbà tí ìwà burúkú bá dé, ẹ̀gàn yóo dé, bí àbùkù bá wọlé ìtìjú yóo tẹ̀lé e.
Pín
Kà Owe 18Owe 18:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Aṣiwère kò ni inu-didùn si imoye, ṣugbọn ki o le fi aiya ara rẹ̀ hàn. Nigbati enia-buburu ba de, nigbana ni ẹ̀gan de, ati pẹlu ẹ̀gan ni itiju.

Kà Owe 18Owe 18:2-3 Yoruba Bible (YCE)

Kà Owe 18