Owe 15:22-23
Owe 15:22-23 Bibeli Mimọ (YBCV)
Laisi ìgbimọ, èro a dasan; ṣugbọn li ọ̀pọlọpọ ìgbimọ, nwọn a fi idi mulẹ. Enia ni ayọ̀ nipa idahùn ẹnu rẹ̀; ati ọ̀rọ kan li akoko rẹ̀, o ti wọ̀ to?
Pín
Kà Owe 15Owe 15:22-23 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Owe 15