Owe 11:18-19
Owe 11:18-19 Yoruba Bible (YCE)
Owó ọ̀yà èké ni eniyan burúkú óo gbà, ṣugbọn ẹni tí ó bá hùwà òdodo yóo gba èrè òtítọ́. Ẹni tí ó dúró ṣinṣin lórí òdodo yóo yè, ṣugbọn ẹni tí ó bá ń lépa ibi yóo kú.
Pín
Kà Owe 11Owó ọ̀yà èké ni eniyan burúkú óo gbà, ṣugbọn ẹni tí ó bá hùwà òdodo yóo gba èrè òtítọ́. Ẹni tí ó dúró ṣinṣin lórí òdodo yóo yè, ṣugbọn ẹni tí ó bá ń lépa ibi yóo kú.