Filp 4:19
Filp 4:19 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn Ọlọrun mi yio pèse ni kikún fun gbogbo aini nyin, gẹgẹ bi ọrọ̀ rẹ̀ ninu ogo ninu Kristi Jesu.
Pín
Kà Filp 4Filp 4:19 Yoruba Bible (YCE)
Ọlọrun mi yóo pèsè fún gbogbo àìní ẹ̀yin náà, gẹ́gẹ́ bí ọpọlọpọ ọrọ̀ rẹ̀ tí ó lógo nípasẹ̀ Jesu Kristi.
Pín
Kà Filp 4