Filp 3:10-11
Filp 3:10-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Èmi mọ̀ ọ́n, àti agbára àjíǹde rẹ̀, àti láti jẹ́ alábápín nínú ìyà rẹ̀ nígbà tí mo bá fi ara mọ́ ọn nínú ikú rẹ̀; nípasẹ̀ bẹ́ẹ̀ kí èmi lè ní àjíǹde kúrò nínú òkú.
Pín
Kà Filp 3