Filp 2:13
Filp 2:13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitoripe Ọlọrun ni nṣiṣẹ ninu nyin, lati fẹ ati lati ṣiṣẹ fun ifẹ inu rere rẹ̀.
Pín
Kà Filp 2Filp 2:13 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí pé Ọlọrun ní ń fun yín ní agbára, láti fẹ́ ṣe ìfẹ́ rẹ̀, ati láti lè ṣe ohun tí ó wù ú.
Pín
Kà Filp 2