File 1:23-25
File 1:23-25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Epafra, ondè ẹlẹgbẹ mi ninu Kristi Jesu kí ọ; Marku, Aristarku, Dema, Luku, awọn olubaṣiṣẹ mi kí ọ pẹlu. Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa wa ki o wà pẹlu ẹmí nyin. Amin.
Pín
Kà File 1Epafra, ondè ẹlẹgbẹ mi ninu Kristi Jesu kí ọ; Marku, Aristarku, Dema, Luku, awọn olubaṣiṣẹ mi kí ọ pẹlu. Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa wa ki o wà pẹlu ẹmí nyin. Amin.