Neh 4:8
Neh 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Gbogbo wọn jọ gbìmọ̀ pọ̀ láti wá bá Jerusalẹmu jà àti láti dìde wàhálà sí í.
Pín
Kà Neh 4Neh 4:8 Yoruba Bible (YCE)
Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí dìtẹ̀ láti wá gbógun ti Jerusalẹmu kí wọ́n lè dá rúkèrúdò sílẹ̀.
Pín
Kà Neh 4Neh 4:8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbogbo wọn si jọ gbìmọ pọ̀ lati wá iba Jerusalemu jà, ati lati ṣe ika si i.
Pín
Kà Neh 4