Mak 2:27-28
Mak 2:27-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ó sì wí fún wọ́n pé, a dá ọjọ́ ìsinmi fún ènìyàn, “Ṣùgbọ́n a kò dá ènìyàn fún ọjọ́ ìsinmi. Nítorí náà Ọmọ Ènìyàn ni Olúwa ọjọ́ ìsinmi pẹ̀lú.”
Pín
Kà Mak 2Mak 2:27-28 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si wi fun wọn pe, A dá ọjọ isimi nitori enia, a kò dá enia nitori ọjọ isimi: Nitorina Ọmọ-enia li oluwa ọjọ isimi pẹlu.
Pín
Kà Mak 2